Ẹ́kísódù 32:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ó mú ère ọmọ màlúù tí wọ́n ṣe, ó fi iná sun ún, ó sì fọ́ ọ túútúú tó fi di lẹ́búlẹ́bú;+ ó wá fọ́n ọn sójú omi, ó sì mú kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì mu ún.+
20 Ó mú ère ọmọ màlúù tí wọ́n ṣe, ó fi iná sun ún, ó sì fọ́ ọ túútúú tó fi di lẹ́búlẹ́bú;+ ó wá fọ́n ọn sójú omi, ó sì mú kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì mu ún.+