Ẹ́kísódù 17:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó wá pe ibẹ̀ ní Másà*+ àti Mẹ́ríbà,*+ torí pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bá a jà àti pé wọ́n dán Jèhófà wò,+ wọ́n ní: “Ṣé Jèhófà wà láàárín wa àbí kò sí?”
7 Ó wá pe ibẹ̀ ní Másà*+ àti Mẹ́ríbà,*+ torí pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bá a jà àti pé wọ́n dán Jèhófà wò,+ wọ́n ní: “Ṣé Jèhófà wà láàárín wa àbí kò sí?”