-
Ẹ́kísódù 34:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Mósè wá sọ̀ kalẹ̀ látorí Òkè Sínáì, àwọn wàláà Ẹ̀rí méjì náà sì wà lọ́wọ́ rẹ̀.+ Nígbà tó sọ̀ kalẹ̀ látorí òkè náà, Mósè ò mọ̀ pé ìtànṣán ń jáde lára awọ ojú òun torí ó ti ń bá Ọlọ́run sọ̀rọ̀.
-