Òwe 7:1-3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọmọ mi, pa àwọn ọ̀rọ̀ mi mọ́,Kí o sì fi àwọn àṣẹ mi ṣe ìṣúra rẹ. + 2 Pa àwọn àṣẹ mi mọ́ kí o sì wà láàyè;+Pa ẹ̀kọ́* mi mọ́ bí ọmọlójú rẹ. 3 So wọ́n mọ́ ìka rẹ;Kọ wọ́n sí wàláà ọkàn rẹ. +
7 Ọmọ mi, pa àwọn ọ̀rọ̀ mi mọ́,Kí o sì fi àwọn àṣẹ mi ṣe ìṣúra rẹ. + 2 Pa àwọn àṣẹ mi mọ́ kí o sì wà láàyè;+Pa ẹ̀kọ́* mi mọ́ bí ọmọlójú rẹ. 3 So wọ́n mọ́ ìka rẹ;Kọ wọ́n sí wàláà ọkàn rẹ. +