Diutarónómì 30:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Wò ó, mo fi ìyè àti ire, ikú àti ibi+ sí iwájú rẹ lónìí.