2 Kíróníkà 7:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà wá fara han Sólómọ́nì+ ní òru, ó sì sọ fún un pé: “Mo ti gbọ́ àdúrà rẹ, mo sì ti yan ibí yìí fún ara mi láti jẹ́ ilé ìrúbọ.+
12 Jèhófà wá fara han Sólómọ́nì+ ní òru, ó sì sọ fún un pé: “Mo ti gbọ́ àdúrà rẹ, mo sì ti yan ibí yìí fún ara mi láti jẹ́ ilé ìrúbọ.+