-
Léfítíkù 17:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 “‘“Tí ọkùnrin kankan ní ilé Ísírẹ́lì bá pa akọ màlúù tàbí ọmọ àgbò tàbí ewúrẹ́ nínú ibùdó tàbí tó pa á ní ẹ̀yìn ibùdó, 4 dípò kó mú un wá sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé láti fi ṣe ọrẹ fún Jèhófà níwájú àgọ́ ìjọsìn Jèhófà, ọkùnrin náà máa jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀. Ó ti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀, ṣe ni kí ẹ pa á, kí ẹ lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.
-