-
Léfítíkù 11:2-4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Ẹ sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Àwọn ohun alààyè tó wà ní ayé* tí ẹ lè jẹ+ nìyí: 3 Ẹ lè jẹ gbogbo ẹran tí pátákò rẹ̀ là, tí pátákò rẹ̀ ní àlàfo, tó sì ń jẹ àpọ̀jẹ.
4 “‘Àmọ́ ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ àwọn ẹran yìí tó ń jẹ àpọ̀jẹ tàbí àwọn tí pátákò wọn là: ràkúnmí máa ń jẹ àpọ̀jẹ, àmọ́ pátákò rẹ̀ kò là. Aláìmọ́ ló jẹ́ fún yín.+
-