-
Gálátíà 1:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àmọ́ ṣá o, bí àwa tàbí áńgẹ́lì kan láti ọ̀run bá kéde ohun kan fún yín pé ó jẹ́ ìhìn rere, àmọ́ tó yàtọ̀ sí ìhìn rere tí a ti kéde fún yín, kí ó di ẹni ègún.
-