Léfítíkù 11:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ẹ sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Àwọn ohun alààyè tó wà ní ayé* tí ẹ lè jẹ+ nìyí: 3 Ẹ lè jẹ gbogbo ẹran tí pátákò rẹ̀ là, tí pátákò rẹ̀ ní àlàfo, tó sì ń jẹ àpọ̀jẹ.
2 “Ẹ sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Àwọn ohun alààyè tó wà ní ayé* tí ẹ lè jẹ+ nìyí: 3 Ẹ lè jẹ gbogbo ẹran tí pátákò rẹ̀ là, tí pátákò rẹ̀ ní àlàfo, tó sì ń jẹ àpọ̀jẹ.