ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 11:4-8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 “‘Àmọ́ ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ àwọn ẹran yìí tó ń jẹ àpọ̀jẹ tàbí àwọn tí pátákò wọn là: ràkúnmí máa ń jẹ àpọ̀jẹ, àmọ́ pátákò rẹ̀ kò là. Aláìmọ́ ló jẹ́ fún yín.+ 5 Bákan náà, gara orí àpáta  + máa ń jẹ àpọ̀jẹ, àmọ́ pátákò rẹ̀ kò là. Aláìmọ́ ló jẹ́ fún yín. 6 Ehoro pẹ̀lú máa ń jẹ àpọ̀jẹ, àmọ́ pátákò rẹ̀ kò là. Aláìmọ́ ló jẹ́ fún yín. 7 Bákan náà ni ẹlẹ́dẹ̀,+ torí pátákò rẹ̀ là, ó sì ní àlàfo, àmọ́ kì í jẹ àpọ̀jẹ. Aláìmọ́ ló jẹ́ fún yín. 8 Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ èyíkéyìí nínú ẹran wọn, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ fara kan òkú wọn. Aláìmọ́ ni wọ́n jẹ́ fún yín.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́