-
Léfítíkù 11:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “‘Èyí tí ẹ lè jẹ nínú gbogbo ohun tó wà nínú omi nìyí: Ẹ lè jẹ+ ohunkóhun tó wà nínú omi tó ní lẹ́bẹ́ àti ìpẹ́, ì báà jẹ́ inú òkun tàbí inú odò ló wà. 10 Àmọ́ ohunkóhun tó wà nínú òkun àti odò tí kò ní lẹ́bẹ́ àti ìpẹ́, nínú gbogbo ẹ̀dá tó ń gbá yìn-ìn àti gbogbo ohun alààyè* míì tó wà nínú omi, ohun ìríra ló jẹ́ fún yín.
-