Nọ́ńbà 14:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Torí pé àfonífojì* ni àwọn ọmọ Ámálékì àti àwọn ọmọ Kénáánì+ ń gbé, kí ẹ ṣẹ́rí pa dà lọ́la, kí ẹ sì gba ọ̀nà Òkun Pupa+ lọ sínú aginjù.”
25 Torí pé àfonífojì* ni àwọn ọmọ Ámálékì àti àwọn ọmọ Kénáánì+ ń gbé, kí ẹ ṣẹ́rí pa dà lọ́la, kí ẹ sì gba ọ̀nà Òkun Pupa+ lọ sínú aginjù.”