-
1 Kọ́ríńtì 16:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ní gbogbo ọjọ́ kìíní ọ̀sẹ̀, kí kálukú yín ya ohun kan sọ́tọ̀ bí agbára rẹ̀ bá ṣe tó, kó má bàa sí pé ẹ̀ ń kó nǹkan jọ nígbà tí mo bá dé.
-