Ẹ́kísódù 34:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ṣùgbọ́n kí ẹ wó àwọn pẹpẹ wọn, kí ẹ sì fọ́ àwọn ọwọ̀n òrìṣà wọn túútúú, kí ẹ sì wó àwọn òpó òrìṣà* wọn lulẹ̀.+
13 Ṣùgbọ́n kí ẹ wó àwọn pẹpẹ wọn, kí ẹ sì fọ́ àwọn ọwọ̀n òrìṣà wọn túútúú, kí ẹ sì wó àwọn òpó òrìṣà* wọn lulẹ̀.+