-
Jòhánù 8:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Bákan náà, a kọ ọ́ sínú Òfin yín pé: ‘Òótọ́ ni ẹ̀rí ẹni méjì.’+
-
-
Hébérù 10:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 A kì í ṣàánú ẹnikẹ́ni tí kò bá ka Òfin Mósè sí, ó máa kú tí ẹni méjì tàbí mẹ́ta bá ti jẹ́rìí sí i.+
-