Diutarónómì 32:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nígbà tí Ẹni Gíga Jù Lọ fún àwọn orílẹ̀-èdè ní ogún+ wọn,Nígbà tó ya àwọn ọmọ Ádámù* sọ́tọ̀ọ̀tọ̀,+Ó pààlà fún àwọn èèyàn+Gẹ́gẹ́ bí iye àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ Jóṣúà 24:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 mo sì fún Ísákì ní Jékọ́bù àti Ísọ̀.+ Lẹ́yìn náà, mo fún Ísọ̀ ní Òkè Séírì pé kó di tirẹ̀;+ Jékọ́bù àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì lọ sí Íjíbítì.+ Ìṣe 17:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Láti ara ọkùnrin kan ló ti dá+ àwọn èèyàn gbogbo orílẹ̀-èdè láti máa gbé lórí gbogbo ilẹ̀ ayé,+ ó yan àkókò fún àwọn nǹkan, ó sì pa ààlà ibi tí àwọn èèyàn á máa gbé,+
8 Nígbà tí Ẹni Gíga Jù Lọ fún àwọn orílẹ̀-èdè ní ogún+ wọn,Nígbà tó ya àwọn ọmọ Ádámù* sọ́tọ̀ọ̀tọ̀,+Ó pààlà fún àwọn èèyàn+Gẹ́gẹ́ bí iye àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+
4 mo sì fún Ísákì ní Jékọ́bù àti Ísọ̀.+ Lẹ́yìn náà, mo fún Ísọ̀ ní Òkè Séírì pé kó di tirẹ̀;+ Jékọ́bù àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì lọ sí Íjíbítì.+
26 Láti ara ọkùnrin kan ló ti dá+ àwọn èèyàn gbogbo orílẹ̀-èdè láti máa gbé lórí gbogbo ilẹ̀ ayé,+ ó yan àkókò fún àwọn nǹkan, ó sì pa ààlà ibi tí àwọn èèyàn á máa gbé,+