Nọ́ńbà 35:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Kí ẹ yan àwọn ìlú tó rọ̀ yín lọ́rùn láti fi ṣe ìlú ààbò, tí ẹni* tó bá ṣèèṣì pa èèyàn* máa sá lọ.+
11 Kí ẹ yan àwọn ìlú tó rọ̀ yín lọ́rùn láti fi ṣe ìlú ààbò, tí ẹni* tó bá ṣèèṣì pa èèyàn* máa sá lọ.+