-
Diutarónómì 31:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Mósè wá kọ Òfin yìí,+ ó sì fún àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì, tí wọ́n ń gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà àti gbogbo àgbààgbà Ísírẹ́lì.
-