Jóṣúà 13:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi idà pa Báláámù+ ọmọ Béórì, tó jẹ́ woṣẹ́woṣẹ́+ pẹ̀lú àwọn yòókù tí wọ́n pa.