Jòhánù 12:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Torí èrò ara mi kọ́ ni mò ń sọ, àmọ́ Baba tó rán mi fúnra rẹ̀ ti fún mi ní àṣẹ kan nípa ohun tí màá wí àti ohun tí màá sọ.+ Hébérù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní báyìí, ní òpin àwọn ọjọ́ yìí, ó ti bá wa sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ Ọmọ+ tó yàn ṣe ajogún ohun gbogbo,+ nípasẹ̀ ẹni tó dá àwọn ètò àwọn nǹkan.*+
49 Torí èrò ara mi kọ́ ni mò ń sọ, àmọ́ Baba tó rán mi fúnra rẹ̀ ti fún mi ní àṣẹ kan nípa ohun tí màá wí àti ohun tí màá sọ.+
2 Ní báyìí, ní òpin àwọn ọjọ́ yìí, ó ti bá wa sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ Ọmọ+ tó yàn ṣe ajogún ohun gbogbo,+ nípasẹ̀ ẹni tó dá àwọn ètò àwọn nǹkan.*+