Diutarónómì 27:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá sún ààlà ọmọnìkejì rẹ̀.’+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)