Òwe 19:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹlẹ́rìí èké kò ní lọ láìjìyà,+Ẹni tí kò sì lè ṣe kó má parọ́ kò ní yè bọ́.+