-
Àìsáyà 26:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Torí pé, wò ó! Jèhófà ń bọ̀ láti àyè rẹ̀,
Láti pe àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà pé kí wọ́n wá jẹ́jọ́ torí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,
Ilẹ̀ náà sì máa tú ìtàjẹ̀sílẹ̀ rẹ̀ síta,
Kò ní lè bo àwọn èèyàn rẹ̀ tí wọ́n pa, bó ṣe ń ṣe tẹ́lẹ̀.”
-
-
Jeremáyà 26:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Àmọ́, kó dá yín lójú pé, bí ẹ bá pa mí, ẹ ó mú ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ wá sórí ara yín àti sórí ìlú yìí àti sórí àwọn tó ń gbé ibẹ̀, torí pé òótọ́ ni Jèhófà rán mi sí yín pé kí n sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí létí yín.”
-