Róòmù 13:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ jẹ́ ká máa rìn lọ́nà tó bójú mu+ bí ìgbà téèyàn ń rìn ní ọ̀sán, kì í ṣe nínú àwọn àríyá aláriwo àti ìmutípara, kì í ṣe nínú ìṣekúṣe àti ìwà àìnítìjú,*+ kì í ṣe nínú wàhálà àti owú.+ 1 Kọ́ríńtì 6:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 àwọn olè, àwọn olójúkòkòrò,+ àwọn ọ̀mùtípara,+ àwọn pẹ̀gànpẹ̀gàn* àti àwọn alọ́nilọ́wọ́gbà kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run.+ Éfésù 5:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Bákan náà, ẹ má ṣe máa mu wáìnì ní àmupara,+ torí ó ń yọrí sí ìwà pálapàla,* àmọ́ ẹ máa kún fún ẹ̀mí.
13 Ẹ jẹ́ ká máa rìn lọ́nà tó bójú mu+ bí ìgbà téèyàn ń rìn ní ọ̀sán, kì í ṣe nínú àwọn àríyá aláriwo àti ìmutípara, kì í ṣe nínú ìṣekúṣe àti ìwà àìnítìjú,*+ kì í ṣe nínú wàhálà àti owú.+
10 àwọn olè, àwọn olójúkòkòrò,+ àwọn ọ̀mùtípara,+ àwọn pẹ̀gànpẹ̀gàn* àti àwọn alọ́nilọ́wọ́gbà kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run.+
18 Bákan náà, ẹ má ṣe máa mu wáìnì ní àmupara,+ torí ó ń yọrí sí ìwà pálapàla,* àmọ́ ẹ máa kún fún ẹ̀mí.