Diutarónómì 13:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 O gbọ́dọ̀ sọ ọ́ lókùúta pa,+ torí ó fẹ́ mú ọ kúrò lọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run rẹ, ẹni tó mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, kúrò ní ilé ẹrú. 11 Nígbà náà, ẹ̀rù á ba gbogbo Ísírẹ́lì tí wọ́n bá gbọ́, wọn ò sì ní dán ohun tó burú bẹ́ẹ̀ wò mọ́ láàárín rẹ.+
10 O gbọ́dọ̀ sọ ọ́ lókùúta pa,+ torí ó fẹ́ mú ọ kúrò lọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run rẹ, ẹni tó mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, kúrò ní ilé ẹrú. 11 Nígbà náà, ẹ̀rù á ba gbogbo Ísírẹ́lì tí wọ́n bá gbọ́, wọn ò sì ní dán ohun tó burú bẹ́ẹ̀ wò mọ́ láàárín rẹ.+