ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 15:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé wọ́n gbọ́dọ̀ máa ṣe wajawaja sí etí aṣọ wọn nísàlẹ̀ jálẹ̀ àwọn ìran wọn, kí wọ́n sì máa fi okùn tín-ín-rín aláwọ̀ búlúù sókè wajawaja tó wà nísàlẹ̀ aṣọ+ wọn.

  • Mátíù 23:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn Farisí ti fi ara wọn sí orí ìjókòó Mósè.

  • Mátíù 23:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Torí kí àwọn èèyàn lè rí wọn ni wọ́n ṣe ń ṣe gbogbo ohun tí wọ́n ń ṣe,+ wọ́n fẹ àwọn akóló tí wọ́n ń kó ìwé mímọ́ sí, èyí tí wọ́n ń dè mọ́ra láti dáàbò bo ara wọn,*+ wọ́n sì mú kí wajawaja etí aṣọ wọn gùn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́