ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 25:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Tí ẹgba bá tọ́ sí ẹni burúkú náà,+ kí adájọ́ dá a dọ̀bálẹ̀, kí wọ́n sì nà án níṣojú rẹ̀. Bí ohun tó ṣe bá ṣe burú tó ni kí iye ẹgba tó máa jẹ ṣe pọ̀ tó.

  • Òwe 10:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ọgbọ́n wà ní ètè olóye,+

      Àmọ́ ọ̀pá wà fún ẹ̀yìn ẹni tí kò ní làákàyè.*+

  • Òwe 19:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Ìdájọ́ ń dúró de àwọn afiniṣẹ̀sín,+

      Ẹgba sì ń dúró de ẹ̀yìn àwọn òmùgọ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́