Málákì 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí mo kórìíra* ìkọ̀sílẹ̀,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí, “mo sì kórìíra ẹni tí ìwà ipá ti wọ̀ lẹ́wù,”* ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí. “Ẹ ṣọ́ ẹ̀mí tó ń darí yín, ẹ má sì hùwà àìṣòótọ́.+
16 Torí mo kórìíra* ìkọ̀sílẹ̀,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí, “mo sì kórìíra ẹni tí ìwà ipá ti wọ̀ lẹ́wù,”* ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí. “Ẹ ṣọ́ ẹ̀mí tó ń darí yín, ẹ má sì hùwà àìṣòótọ́.+