1 Kọ́ríńtì 10:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé gbogbo àwọn baba ńlá wa wà lábẹ́ ìkùukùu,*+ gbogbo wọn gba inú òkun kọjá,+ 1 Kọ́ríńtì 10:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Síbẹ̀, a pa wọ́n nínú aginjù+ nítorí inú Ọlọ́run kò dùn sí èyí tó pọ̀ jù lára wọn.
10 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé gbogbo àwọn baba ńlá wa wà lábẹ́ ìkùukùu,*+ gbogbo wọn gba inú òkun kọjá,+