-
Jẹ́nẹ́sísì 46:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Wọ́n kó agbo ẹran wọn àti ẹrù wọn dání, èyí tí wọ́n ti ní nílẹ̀ Kénáánì. Jékọ́bù àti gbogbo àwọn ọmọ rẹ̀ wá dé sí ilẹ̀ Íjíbítì.
-
-
Sáàmù 105:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Lẹ́yìn náà, Ísírẹ́lì wá sí Íjíbítì,+
Jékọ́bù sì di àjèjì ní ilẹ̀ Hámù.
-