ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 21:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Dáfídì dá àlùfáà náà lóhùn pé: “A ti rí i dájú pé a yẹra fún àwọn obìnrin bí a ti máa ń ṣe nígbà tí mo bá jáde ogun.+ Tí ara àwọn ọkùnrin náà bá wà ní mímọ́ nígbà tó jẹ́ pé iṣẹ́ tí kò fi bẹ́ẹ̀ ṣe pàtàkì ni wọ́n bá lọ, ṣé wọn ò ní wà ní mímọ́ nígbà tí wọ́n fẹ́ ṣiṣẹ́ pàtàkì bíi tòní yìí?”

  • 2 Sámúẹ́lì 11:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ùráyà dá Dáfídì lóhùn pé: “Àpótí  + àti gbogbo ọmọ ogun Ísírẹ́lì àti ti Júdà ń gbé lábẹ́ àtíbàbà, olúwa mi Jóábù àti àwọn ìránṣẹ́ olúwa mi sì pàgọ́ sórí pápá. Ṣé ó wá yẹ kí n lọ sínú ilé mi láti jẹ àti láti mu àti láti bá ìyàwó mi sùn?+ Bí o ti wà láàyè, tí o sì ń mí,* mi ò jẹ́ ṣe nǹkan yìí!”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́