Ẹ́kísódù 22:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “Tí o bá gba aṣọ ọmọnìkejì rẹ láti fi ṣe ìdúró,*+ kí o dá a pa dà fún un nígbà tí oòrùn bá wọ̀. 27 Ohun kan ṣoṣo tó bò ó lára nìyẹn, aṣọ tó fi bo ara* rẹ̀; kí wá ni kó fi bora sùn?+ Tó bá ké pè mí, ó dájú pé màá gbọ́, torí mo jẹ́ aláàánú.*+
26 “Tí o bá gba aṣọ ọmọnìkejì rẹ láti fi ṣe ìdúró,*+ kí o dá a pa dà fún un nígbà tí oòrùn bá wọ̀. 27 Ohun kan ṣoṣo tó bò ó lára nìyẹn, aṣọ tó fi bo ara* rẹ̀; kí wá ni kó fi bora sùn?+ Tó bá ké pè mí, ó dájú pé màá gbọ́, torí mo jẹ́ aláàánú.*+