-
Rúùtù 4:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Torí náà, Bóásì sọ pé: “Ní ọjọ́ tí o bá ra ilẹ̀ náà lọ́wọ́ Náómì, o tún gbọ́dọ̀ rà á lọ́wọ́ Rúùtù ará Móábù, aya ọkùnrin tó ti kú náà, kí o lè dá orúkọ ọkùnrin tó ti kú náà pa dà sórí ogún rẹ̀.”+
-
-
Máàkù 12:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 “Olùkọ́, Mósè kọ̀wé fún wa pé tí arákùnrin ẹnì kan bá kú, tó sì fi ìyàwó sílẹ̀ àmọ́ tí kò bímọ, kí arákùnrin rẹ̀ fẹ́ ìyàwó rẹ̀, kó sì bímọ fún arákùnrin rẹ̀.+
-