Jẹ́nẹ́sísì 28:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ísákì wá ní kí Jékọ́bù máa lọ, ó sì forí lé Padani-árámù, ó lọ sọ́dọ̀ Lábánì ọmọ Bẹ́túẹ́lì ará Arémíà,+ arákùnrin Rèbékà + tó jẹ́ ìyá Jékọ́bù àti Ísọ̀. Hósíà 12:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jékọ́bù sá lọ sí agbègbè* Árámù;*+Ísírẹ́lì+ ṣiṣẹ́ níbẹ̀ nítorí àtifẹ́ ìyàwó,+Ó sì ń da àgùntàn nítorí ìyàwó.+
5 Ísákì wá ní kí Jékọ́bù máa lọ, ó sì forí lé Padani-árámù, ó lọ sọ́dọ̀ Lábánì ọmọ Bẹ́túẹ́lì ará Arémíà,+ arákùnrin Rèbékà + tó jẹ́ ìyá Jékọ́bù àti Ísọ̀.
12 Jékọ́bù sá lọ sí agbègbè* Árámù;*+Ísírẹ́lì+ ṣiṣẹ́ níbẹ̀ nítorí àtifẹ́ ìyàwó,+Ó sì ń da àgùntàn nítorí ìyàwó.+