Diutarónómì 11:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 “Tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá mú ọ dé ilẹ̀ tó máa di tìrẹ, kí o súre* ní Òkè Gérísímù, kí o sì gégùn-ún ní Òkè Ébálì.+
29 “Tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá mú ọ dé ilẹ̀ tó máa di tìrẹ, kí o súre* ní Òkè Gérísímù, kí o sì gégùn-ún ní Òkè Ébálì.+