Diutarónómì 7:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Kí ẹ dáná sun ère àwọn ọlọ́run wọn tí wọ́n gbẹ́.+ Má ṣe jẹ́ kí ojú rẹ wọ fàdákà àti wúrà tó wà lára wọn, o ò sì gbọ́dọ̀ mú un fún ara rẹ,+ kó má bàa jẹ́ ìdẹkùn fún ọ, torí ohun ìríra ló jẹ́ lójú Jèhófà Ọlọ́run rẹ.+ Diutarónómì 29:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹ sì máa ń rí àwọn ohun ìríra wọn àti àwọn òrìṣà ẹ̀gbin*+ wọn, tí wọ́n fi igi, òkúta, fàdákà àti wúrà ṣe, tó wà láàárín wọn.)
25 Kí ẹ dáná sun ère àwọn ọlọ́run wọn tí wọ́n gbẹ́.+ Má ṣe jẹ́ kí ojú rẹ wọ fàdákà àti wúrà tó wà lára wọn, o ò sì gbọ́dọ̀ mú un fún ara rẹ,+ kó má bàa jẹ́ ìdẹkùn fún ọ, torí ohun ìríra ló jẹ́ lójú Jèhófà Ọlọ́run rẹ.+
17 Ẹ sì máa ń rí àwọn ohun ìríra wọn àti àwọn òrìṣà ẹ̀gbin*+ wọn, tí wọ́n fi igi, òkúta, fàdákà àti wúrà ṣe, tó wà láàárín wọn.)