-
Mátíù 27:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nígbà tí Júdásì, ẹni tó dà á, rí i pé wọ́n ti dá Jésù lẹ́bi, ẹ̀dùn ọkàn bá a, ó sì kó ọgbọ̀n (30) ẹyọ fàdákà náà pa dà wá fún àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà,+ 4 ó sọ pé: “Mo dẹ́ṣẹ̀ nígbà tí mo fi ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ lé yín lọ́wọ́.” Wọ́n sọ pé: “Kí ló kàn wá pẹ̀lú ìyẹn? Ìwọ ni kí o lọ wá nǹkan ṣe sí i!”*
-