Léfítíkù 26:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “‘Tí ẹ bá ń tẹ̀ lé àwọn òfin mi, tí ẹ̀ ń pa àwọn àṣẹ mi mọ́, tí ẹ sì ń ṣe wọ́n,+ 4 èmi yóò rọ ọ̀wààrà òjò fún yín ní àkókò tó yẹ,+ ilẹ̀ yóò mú èso jáde,+ àwọn igi oko yóò sì so èso. Òwe 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ìbùkún Jèhófà ló ń sọni di ọlọ́rọ̀,+Kì í sì í fi ìrora* kún un. Àìsáyà 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Tó bá tinú yín wá, tí ẹ sì fetí sílẹ̀,Ẹ máa jẹ àwọn ohun rere ilẹ̀ náà.+
3 “‘Tí ẹ bá ń tẹ̀ lé àwọn òfin mi, tí ẹ̀ ń pa àwọn àṣẹ mi mọ́, tí ẹ sì ń ṣe wọ́n,+ 4 èmi yóò rọ ọ̀wààrà òjò fún yín ní àkókò tó yẹ,+ ilẹ̀ yóò mú èso jáde,+ àwọn igi oko yóò sì so èso.