-
Jóṣúà 13:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Mósè pín ogún fún ẹ̀yà àwọn ọmọ Rúbẹ́nì ní ìdílé-ìdílé,
-
-
Jóṣúà 21:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe fi kèké pín àwọn ìlú yìí àtàwọn ibi ìjẹko wọn fún àwọn ọmọ Léfì nìyẹn, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+
-
-
Jóṣúà 21:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Kédémótì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Mẹ́fáátì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, ó jẹ́ ìlú mẹ́rin.
-