-
Diutarónómì 7:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ó máa nífẹ̀ẹ́ rẹ, ó máa bù kún ọ, ó sì máa sọ ọ́ di púpọ̀. Àní, ó máa fi ọmọ púpọ̀ bù kún ọ,*+ ó máa fi èso ilẹ̀ rẹ bù kún ọ, ó sì máa fi ọkà rẹ, wáìnì tuntun rẹ, òróró rẹ,+ àwọn ọmọ màlúù nínú ọ̀wọ́ ẹran rẹ àti àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn nínú agbo ẹran rẹ bù kún ọ ní ilẹ̀ tó búra fún àwọn baba ńlá rẹ pé òun máa fún ọ.+
-