2 Kíróníkà 29:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Idà ti pa àwọn baba ńlá wa,+ àwọn ọmọkùnrin wa, àwọn ọmọbìnrin wa àti àwọn ìyàwó wa sì ti lọ sóko ẹrú nítorí nǹkan yìí.+
9 Idà ti pa àwọn baba ńlá wa,+ àwọn ọmọkùnrin wa, àwọn ọmọbìnrin wa àti àwọn ìyàwó wa sì ti lọ sóko ẹrú nítorí nǹkan yìí.+