Nehemáyà 9:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Ọ̀pọ̀ àwọn ohun rere tí ilẹ̀ náà ń mú jáde jẹ́ ti àwọn ọba tí o fi ṣe olórí wa nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa.+ Wọ́n ń ṣàkóso àwa* àti àwọn ẹran ọ̀sìn wa bó ṣe wù wọ́n, a sì wà nínú wàhálà ńlá. Àìsáyà 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ilẹ̀ yín ti di ahoro. Wọ́n ti dáná sun àwọn ìlú yín. Àwọn àjèjì jẹ ilẹ̀ yín run níṣojú yín.+ Ó dà bí ilẹ̀ tó di ahoro tí àwọn àjèjì gbà.+
37 Ọ̀pọ̀ àwọn ohun rere tí ilẹ̀ náà ń mú jáde jẹ́ ti àwọn ọba tí o fi ṣe olórí wa nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa.+ Wọ́n ń ṣàkóso àwa* àti àwọn ẹran ọ̀sìn wa bó ṣe wù wọ́n, a sì wà nínú wàhálà ńlá.
7 Ilẹ̀ yín ti di ahoro. Wọ́n ti dáná sun àwọn ìlú yín. Àwọn àjèjì jẹ ilẹ̀ yín run níṣojú yín.+ Ó dà bí ilẹ̀ tó di ahoro tí àwọn àjèjì gbà.+