1 Kọ́ríńtì 10:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn nǹkan yìí ṣẹlẹ̀ sí wọn kí ó lè jẹ́ àpẹẹrẹ fún wa,+ wọ́n sì wà lákọsílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìkìlọ̀ fún àwa tí òpin àwọn ètò àwọn nǹkan dé bá.
11 Àwọn nǹkan yìí ṣẹlẹ̀ sí wọn kí ó lè jẹ́ àpẹẹrẹ fún wa,+ wọ́n sì wà lákọsílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìkìlọ̀ fún àwa tí òpin àwọn ètò àwọn nǹkan dé bá.