-
Jeremáyà 5:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Tí wọ́n bá sì béèrè pé, ‘Kí ló dé tí Jèhófà Ọlọ́run wa fi ṣe gbogbo nǹkan yìí sí wa?’ kí o sọ fún wọn pé, ‘Bí ẹ ṣe fi mí sílẹ̀ láti sin ọlọ́run àjèjì ní ilẹ̀ yín, bẹ́ẹ̀ ni ẹ ó sin àwọn àjèjì ní ilẹ̀ kan tí kì í ṣe tiyín.’”+
-