-
2 Àwọn Ọba 6:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ọba wá béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Kí ni ìṣòro rẹ?” Ó dáhùn pé: “Obìnrin yìí sọ fún mi pé, ‘Mú ọmọ rẹ wá, kí a lè jẹ ẹ́ lónìí, a ó sì jẹ ọmọ tèmi ní ọ̀la.’+
-