Émọ́sì 9:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bí àwọn ọ̀tá bá kó wọn lọ sí oko ẹrú,Ibẹ̀ ni màá ti pàṣẹ fún idà, yóò sì pa wọ́n;+Màá dájú sọ wọ́n, kì í ṣe fún ire, bí kò ṣe fún ibi.+
4 Bí àwọn ọ̀tá bá kó wọn lọ sí oko ẹrú,Ibẹ̀ ni màá ti pàṣẹ fún idà, yóò sì pa wọ́n;+Màá dájú sọ wọ́n, kì í ṣe fún ire, bí kò ṣe fún ibi.+