Ẹ́kísódù 19:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 ‘Ẹ ti fojú ara yín rí ohun tí mo ṣe sí àwọn ará Íjíbítì,+ kí n lè fi àwọn ìyẹ́ idì gbé yín wá sọ́dọ̀ ara mi.+ Jóṣúà 24:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà tó yá, mo rán Mósè àti Áárónì,+ mo sì fi ohun tí mo ṣe láàárín wọn mú ìyọnu bá Íjíbítì,+ mo sì mú yín jáde.
4 ‘Ẹ ti fojú ara yín rí ohun tí mo ṣe sí àwọn ará Íjíbítì,+ kí n lè fi àwọn ìyẹ́ idì gbé yín wá sọ́dọ̀ ara mi.+
5 Nígbà tó yá, mo rán Mósè àti Áárónì,+ mo sì fi ohun tí mo ṣe láàárín wọn mú ìyọnu bá Íjíbítì,+ mo sì mú yín jáde.