Róòmù 11:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ọlọ́run ti fún wọn ní ẹ̀mí oorun àsùnwọra,+ ojú tí kò ríran àti etí tí kò gbọ́ràn, títí di òní olónìí.”+
8 bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ọlọ́run ti fún wọn ní ẹ̀mí oorun àsùnwọra,+ ojú tí kò ríran àti etí tí kò gbọ́ràn, títí di òní olónìí.”+