Ẹ́kísódù 12:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Oríṣiríṣi èèyàn tó pọ̀ rẹpẹtẹ*+ ló tún bá wọn lọ, pẹ̀lú àwọn agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran, ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ ẹran ọ̀sìn.
38 Oríṣiríṣi èèyàn tó pọ̀ rẹpẹtẹ*+ ló tún bá wọn lọ, pẹ̀lú àwọn agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran, ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ ẹran ọ̀sìn.